The significance of Yorùbá oral poetry in language acquisition In Islamics, Scholarship and Service to Humanity: A Festschrift in Honour of Prof. Is-haq Olanrewaju Oloyede.
No Thumbnail Available
Date
2024
Authors
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
The Consortium of Universities in Kwara State (KU8+) University of Ilorin, Ilorin, Nigeria.
Abstract
Ó șe kókó láti mò ohun tí ó ń jẹ́ ìwàdí kí a le mọ pàtàkì àbò ìwádíì jíjé. Gbogbo ìgbésí ayé omo èdá ni ó kún fún àìyé. Àìyé ni ayé fúnra rệ, ohun tí kò yéni, tí a fệ kí aráyé gbó kí ó le șe àwọn ènìyàn tí òrò kàn ní ànfààní ni a ń șe ìwàdí lé lórí., torí náà ìmộ tuntun tí a fi bọ ayé ni. Èrò, òrò tàbí ișé tuntun kan la fẹ́ tà fáyé. Gbogbo ệka ìmò ló ní òfin àti ètò tí ó de ìlànà ìsewadìí, bákan náà ni ìlànà ìjábò gùn lé àwon òté kan. Bí èdè ìwádìí se yàto náà ni èdè ìjábo ìwádìí náà yàto sí èdè gbèfệ. Èròngbà wa ní orí yìí ni láti e àkóyawó àlàyé nípa òfin àti ààtò ìjàbò ìwádìí iș àkànse fún gbígba oyè tàbí ìwé ệrí Bí eè, ni Ệka Ìmộ dá Èdè àti Èdè Nàìjíríà, ní pàtàkì jùlo, ìlànà àti ètò ìjábo ìwádìí ìmo àșà, lítíréșò àti èdè Yorùbá. Ètò tí a tệlé nínú àpilệko yìí ni șíse àlàyé kókó òrò tí ò kan așèwádìí, pípe àkíyèsí won sí ojúse won àti àwon àșìse tí ó wóp láàárin àwọn akékòó, àlàyé àti afihàn ètò ișé láti èèpo yìn dé ìparí àpilèko sì tèlé e.
Description
Chapters in Book
Keywords
Citation
Adéigbe I. A. & Hamzat S. A. O. (2024). The significance of Yorùbá oral poetry in language acquisition In Islamics, Scholarship and Service to Humanity: A Festschrift in Honour of Prof. Is-haq Olanrewaju Oloyede. Adedimeji A. & AbdulGafar O. Fahm (eds.), 155-164. Published by The Consortium of Universities in Kwara State (KU8+) University of Ilorin, Ilorin, Nigeria. ISBN; 978-978-61001-1-1.