Isekariaye ati asa Yoruba: Agbeyewo ewi apileko Aye n yipo

No Thumbnail Available

Date

2008

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

Dept of Linguistics & Nigerian Languages, UNILORIN

Abstract

Kì í se ohun tuntun tàbí ohun èèwò ni kí àwùjo kan mú lára àbùdá àsà àwùjo mìíràn. Nípasè èyí, ìdàgbàsókè àti ìtèsíwájú nípa ètò oró-ajé, ìsèlú, ìmò èro àti ìmò sáyénsí yóò máa bá irú àwùjo béè. Sùgbón ohun tó burú jáì ni kí àsà tí a mú láti ara àbùdá rè kúkú wá gba orí lówó àsà tí a yá a wò. Pàtàkì ohun tí a gbé yèwò nínú isé yìí ni àkóbá tí ètò ìsekáríayé (tàbí ohun tí Adéyemí (2006) pè ní ìso-ayé-dòkan) se fún àsà Yorùbá, pàápàá àsà ìgbéyàwó. A fí ewì àpilèko Ayé n yípo tí Àyángbilé àti Òpádòtun ko se àtègùn. A wo ire àti ibi tó wà nínú ìsekáríayé, gégé bí ó se hàn nínú ewì àpìlèko yìí, pèlú ìmòràn ònà àbáyo nípa pípadà sí àsà ìbílè Yorùbá.

Description

N/A

Keywords

isekariaye, asa igbeyawo Yoruba

Citation

N/A

Collections