Isekariaye ati asa Yoruba: Agbeyewo ewi apileko Aye n yipo

dc.contributor.authorAdeosun, Hezekiah Olufemi
dc.date.accessioned2019-04-15T07:46:00Z
dc.date.available2019-04-15T07:46:00Z
dc.date.issued2008
dc.descriptionN/Aen_US
dc.description.abstractKì í se ohun tuntun tàbí ohun èèwò ni kí àwùjo kan mú lára àbùdá àsà àwùjo mìíràn. Nípasè èyí, ìdàgbàsókè àti ìtèsíwájú nípa ètò oró-ajé, ìsèlú, ìmò èro àti ìmò sáyénsí yóò máa bá irú àwùjo béè. Sùgbón ohun tó burú jáì ni kí àsà tí a mú láti ara àbùdá rè kúkú wá gba orí lówó àsà tí a yá a wò. Pàtàkì ohun tí a gbé yèwò nínú isé yìí ni àkóbá tí ètò ìsekáríayé (tàbí ohun tí Adéyemí (2006) pè ní ìso-ayé-dòkan) se fún àsà Yorùbá, pàápàá àsà ìgbéyàwó. A fí ewì àpilèko Ayé n yípo tí Àyángbilé àti Òpádòtun ko se àtègùn. A wo ire àti ibi tó wà nínú ìsekáríayé, gégé bí ó se hàn nínú ewì àpìlèko yìí, pèlú ìmòràn ònà àbáyo nípa pípadà sí àsà ìbílè Yorùbá.en_US
dc.description.sponsorshipSELFen_US
dc.identifier.citationN/Aen_US
dc.identifier.urihttp://hdl.handle.net/123456789/1750
dc.language.isootheren_US
dc.publisherDept of Linguistics & Nigerian Languages, UNILORINen_US
dc.relation.ispartofseriesvol. 1;2008
dc.subjectisekariayeen_US
dc.subjectasa igbeyawo Yorubaen_US
dc.titleIsekariaye ati asa Yoruba: Agbeyewo ewi apileko Aye n yipoen_US
dc.title.alternativeNILen_US
dc.typeArticleen_US

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
Adeosun Isekariaye Ati Asa Yoruba.pdf
Size:
2.48 MB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
main article
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.69 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description:

Collections