Isowolo-Ede Ofo ninu Asayan Oro ati Afo Yoruba

dc.contributor.authorOkewande, Oluwole Tewogboye
dc.date.accessioned2021-02-03T11:14:31Z
dc.date.available2021-02-03T11:14:31Z
dc.date.issued2018
dc.description.abstractÀmúlò oríṣìíríṣìí àwọn àbùdá ajẹmédè pè fún ìkẹ́sẹjárí, ìpegedé àti ìjágaara àmújáde ìtumọ̀ afọ̀ fún onímọ̀-èdè, nínú ìmọ̀ ìmédèlò. Ṣaájú àkókò yìí, kò tí ì sí iṣẹ́ ìwádìí kan gúnmọ́ lórí àtẹ tó ṣàgbéyẹ̀wò ipa tí àwọn ìlànà ìṣowọ́lò-èdè ìṣọfọ̀ wọ̀nyìí ń kó láwùjọ Yorùbá. À̀làfo yìí niṣẹ́ ìwádìí yìí yóò dí. Nipasẹ̀ èyí, àtubọ̀tán iṣẹ́ yìí ni láti ṣàgbéyẹ̀wò ipa tí ìlò ohùn àti ìró ẹ̀ka-èdè àti èdè àmúlò ń kó nínú ìmèdè bí atọ́ka ìṣọwọ́ afọ̀ fún ìkẹ́sẹjárí-ìlò-èdè àti àgbọ́yé-afọ̀ láwùjọ Yorùbá. Iṣẹ́ yìí ṣàmúlò èdè fáyẹ̀wò láti ara ìsọ̀rí ọfọ̀ látinú oríṣìí afọ̀. Ìtúpalẹ̀ àkójọ-èdè-fáyẹ̀wò inú iṣẹ́ yìí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, ipa tí ìmọ̀ nípa ìlò ohùn àti ìró, èdè-àmúlò àti ẹ̀ka-èdè, bí atọ́ka ìṣọwọ́ afọ̀ ń kó nínú ìmèdè, ìkẹ́sẹjárí-ìlò-èdè, àgbọ́yé-afọ̀ àti ìtumọ̀ kò ṣe é fojú tín-ín-rín rárá. Èyí ni pé, láìsí ìpegedé àti ìjáfáfá aṣafọ̀ nínú ìṣafọ̀ àmúlò àwọn fọ́nrán-èdè fáyẹ̀wò tíṣẹ́ yìí fi ṣàtẹ̀gùn ìtúpalẹ̀, àìgbọ́ra-ẹni-yé, ìtumọ̀-òdì tàbí ìyítumọ̀po ni yóò wáyé nínú ìṣọfọ̀.en_US
dc.identifier.issn0794-4551
dc.identifier.urihttp://hdl.handle.net/123456789/4261
dc.language.isoenen_US
dc.publisherFaculty of Arts, University of Ilorinen_US
dc.relation.ispartofseries27;
dc.subjectÌṣọwọ́lò-èdèen_US
dc.subjectÌṣọwọ́en_US
dc.subjectÌró àti ohùnen_US
dc.subjectÈdè-àmúlòen_US
dc.subjectẸ̀ka-èdèen_US
dc.subjectỌfọ̀en_US
dc.titleIsowolo-Ede Ofo ninu Asayan Oro ati Afo Yorubaen_US
dc.typeArticleen_US

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
10 Isowolo Ede Ofo Ninu Asayan.pdf
Size:
14.41 MB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
Main article
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.69 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description:

Collections