Iha ti Yoruba Ko si Ibalopo Tako-Tabo Laaarin Ibatan Kan naa

Okewande, Oluwole Tewogboye (2018-01)

Article

Nile to mo lonii kaakiri orile-ede agbaye, Afrika ati ni pataki, lorile-ede Naijiria, n se ni oro ibalopo tako-tabo laaarin ibatan, ebi ati idile kan naa n gbile bi owaara ojo.

Collections: