Ifiwadii-sotumo awon iyanrofeere inu oriki oba Ladigbolu kinni ati Adeyemi keta

No Thumbnail Available

Date

2025

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

University of Lagos

Abstract

Bí a bá ta á, à á to ̣̀ ọ́ ni, kó má baà dẹran onídin. Ọ̀ po ̣̀ iṣẹ́ ló ti lọ lórí ìyánrọ̀fẹ́ẹ́rẹ́ nínú lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ṣùgbọ́n , àkíyèsí wa ni pé, kò tíì sị́ ẹni tó ṣiṣẹ́lórí ìyánrọ̀ fẹ́ẹ́rẹ́nínú àwọn oríkì Aláàfin Ọ̀ yọ́. Ìyánrọ̀fẹ́ẹ́rẹ́sì ni àwọ́n o ̣̀ nà tí à á fi í pàṣamọ̀o ̣̀ rọ̀nínú afọ̀láì tú iṣu dé ìsàlẹ̀kòkò tíkò sì ní pa ìtumọ̀afọ̀lára. Ọ̀ pọ̀ìṣẹ̀lẹ̀tó ti wáyé ló kórajọ di oríkì tí ó sìjẹ́pé gbólóhùn àti ọ̀rọ̀po ̣̀ níbẹ̀tí wọ́n lóyún ìtumọ̀sínú. Èròńgbà iṣẹ́ìwádìí yìí ni láti le tọpinpin àwọn ìtàn tí ó rọ̀mọ́oríkì Aláàfin Ládìgbòlùkìíní àti Aláàfin Adeyẹmi kẹta torí pé àwọn méjèèjì ni wọ́n pẹ́jù lóríàpèrè babaa wọn nínú àwọn Aláàfin mẹ́jẹ̀ẹ̀jọ tí wọ́n ti jẹ ní Ọ̀ yọ́ìsìnyíláàrin ọdún 1835 sí 2022. Isẹ́ yìí tọpinpin àwọn ìtumọ̀yìí nípa ṣíṣeàmúlò tíọ́rì ìfìwádìí-sòtumọ̀(Hermaneutics). Ọgbọ́n ìsọ̀t àn O-ṣojúù-mikòróni a gbà fi gbé iṣẹ́náà kálẹ̀gẹ́gé bí akópa nínú oríki Aláàfin O ̣̀ yọ́.

Description

Keywords

Citation

Collections