Àgbéyẹ̀wò Adébóyè Babalọlá gẹ́gẹ́ bi akéwì Yorùbá
No Thumbnail Available
Date
2004
Authors
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
The Association of the Teachers of Yorùbá Language, Department of African Languages and Literatures, Lagos State University, Ojo
Abstract
Àkójopò ewì Adébóyè Babalolá tí a rí nínú Ìwé Ewé Omísínmisìn ní a gbà pé ó ti bệrè láti ọdún 1950 tí ó ti ń fi ewì dánra wò nínú ìwé ìròyìn Yorùbá títí ìwé yìí fi di títè jáde ní odún 1989. Tí a bá wo àkóónú, ìlò èdè àti àgbékalè ewì rè a rí i pé kò le koko, pès ló rộ bí ẹni tí ń tàkurò sọ. Awon òdiwon tí àwon onímò bí Aristotle, Plato,
Coleridge àti Olátúnjí fún ewì bèrệ láti orí kókó òrò àgbékalè títí dé orí ìlò èdè férè má lè jé kí á pe ewì Babalolá ní ewì. Olátúnjí (1995:337) tilệ tóka sí i pé ìtumò àwọn ewì àpilệkọ Yorùbá ti máa ń lọ tààrà jù, kò fara sin nítorí náà wọn ò lè dúró ní ègbé ewì Yorùbá tí Fémi Fátóba ńkọ.
Ìtumọ̀ àkànlò tí Qlátúnjí (1995:33) fúnka mó yìí ló mú wa wo òdiwòn ewì, èdè ewì àti akéwì, láti se àyèwò ewì Babalolá gégé bí akéwì Yorùbá. Njé Adébóyè Babalolá yege òdiwòn akéwì Yorùbá, sé ó tó ní eni tí a le pè ní akéwì Yorùbá. Àwon ìbéèrè tí a ó wá ìdáhùn sí nìyí ní ìparí isé yìí nípa fífi tíórì sosíólójì lítírésò se àtúpalè ewì rệ.
Description
Journal
Keywords
Citation
Hamzat, S. A. O. (2004). Àgbéyẹ̀wò Adébóyè Babalọlá gẹ́gẹ́ bi akéwì Yorùbá. YORÙBÁ GBÒDE: Jọ́nà Ẹgbẹ Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá, Nàìjíríà. 3 (4), 75-85, Published by the Association of the Teachers of Yorùbá Language, Department of African Languages and Literatures, Lagos State University, Ojo. ISSN; 1118-2482.