Agbeyewo Akoonu orin Baluu ni ilu Ilorin

dc.contributor.authorAdeyemi, RO
dc.date.accessioned2026-04-19T13:19:43Z
dc.date.available2026-04-19T13:19:43Z
dc.date.issued2025
dc.description.abstractO ̣̀kan pàtàkì ni orin je ̣́ nínú ewì alohùn Yorùbá. Káríayé ní orin kíkọ jẹ́ láàrin e ̣̀dá ọmọ ènìyàn. Kò sì ṣe é fọwọ́ ro ̣́ se ̣́yìn rárá láwùjọ pàápàá jùlọ ní ile ̣̀ Áfíríkà jákè jádò. Oríṣìí orin ló wà, o ̣̀to ̣̀o ̣̀tọ̀ sì ní ibi, àsìkò àti ìgbà tí a lè kọ wo ̣́n. Síbe ̣̀ náà, káríayé ní orin jẹ́ bẹ́ e ̣̀ sì ní ipa re ̣̀ kò ṣe é fo ̣́wọ́ rọ́ se ̣́yìn láàrin ọmọ ẹ̀ dá. Orin Bàlúù jẹ́ o ̣̀kan lára orin ìbíle ̣̀ Yorùbá ní Ìlọrin. Ọ̀ kan lára ọ̀ nà tí à ń gbà ṣe ìtanijí lórí ìwà ọmọlúàbí, ètò ẹbí àti ìbágbépọ̀ àlàáfíà ní àwùjọ ní wọ́ n ńlo orin yìí fún. Iṣe ̣́ yìí yòó ṣàfihàn ìwúlò orin bàlúù látàrí àkóónú tí a rí fàyọ nínú re ̣̀. Iṣe ̣́ yìí yòó ṣe àtúpale ̣̀ àwọn kókó díe ̣̀ tí àwọn ọ̀ kọrin ma ńṣàmúlò nínú orin ọ̀ hún. Bí Ayé tile ̣̀ tí yàto ̣̀ tí onírúurú orin àti àṣà aláṣà sì tí gbòde kan síbe ̣̀, orin Bàlúù yàto ̣̀ sí pé ó ń dá ní lárayá, tún ńfi kún ọgbo ̣́n, ìmo ̣̀ àti òye ẹ̀ dá nípa kíko ̣́ ní le ̣́ko ̣̀o ̣́ ìwà ọmọlúàbí, ìgbáyégbádùn àti ìbágbépo ̣̀ àlàáfíà ní àwùjọ wa. Nítorí pé lára àṣà ní orin wà, tío ̣́rì àṣà ìbíle ̣̀ ní yòó ràn wá lo ̣́wọ́ jù láti lè ṣe àtúpale ̣̀ àwọn kókó tí a fe ̣́ fàyọ nínú iṣe ̣́ yìí dáadáa nítorí pé, àṣà ní orin; orin l’aṣà.
dc.identifier.urihttps://uilspace.unilorin.edu.ng/handle/123456789/17394
dc.language.isoen
dc.publisherDepartment of Linguistics and Languages, Adekunle Ajasin University
dc.relation.ispartofseries18
dc.titleAgbeyewo Akoonu orin Baluu ni ilu Ilorin
dc.typeArticle

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
2025-A2-NEW ERÉ BÀLÚÙ NÍ ÌLÚ ÌLỌRIN.pdf
Size:
649.41 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description:

Collections