Iha ti Yoruba Ko Si Ifarada Esin Ninu Ero Ati Igbagbo Won

Okewande, Oluwole Tewogboye (2013)

Article

Oro esin kii se ajeji ni awojo omoniyan. Ipa keremi ko ni esin si n ko ninu igbeaye eda ati awujo pelu. Kaakiri agbaye, ati ni pataki, lorile-ede Naijiria lonii; ipa ti ko se e foju rena ni oro esin n ko nidii oro iselu.

Collections: