Àyẹ̀wò ìbáyému nìnù o̩mo̩ olókùn ẹṣin àti ayé dayé òyìnbó YORÙBÁ GBÒDE
| dc.contributor.author | Hamzat, S. A. O. | |
| dc.date.accessioned | 2025-05-07T09:59:15Z | |
| dc.date.available | 2025-05-07T09:59:15Z | |
| dc.date.issued | 2000 | |
| dc.description | Journal | |
| dc.description.abstract | Àkíyèsí àyíká eni ló bí ìrírí eni. Ìrírí ònkowé ní yíká re ni yóò șe okùnfà irú ìtàn tí ònkowé le kọ. Orísirísi ònà ni àwon òùkòwé Yorùbá n gbà ko ìtàn àròso. A ti rí ìtàn òtelèmúyé, èyí tó dá lé ìtàn gidi àti èyí tó ń fi èhónú hàn sí ètò òṣèlú tàbí ohun tí ń lọ ní àwùjo. Èyí tí isé yìí dá lé ni ìtàn àròso tó dá lérí ìtàn gidi to ti selệ rí. Lára ohun tí irú àwọn ìwé yìí máa ń dá lé ni ìgbésí ayé àwon baba ńlá wa, ètò ìșèlú ayé ojóun, bí àwọn ìjòyè àti ológun șe ń darí ìlú, tí wọn ń jayé ta-ní-o-mú-mi tí àwọn mèkúnnù sì ń jìyà. Irú ìtàn àròsọ báyìí tún máa ń la ònà tí àwon ènìyàn, fi le jàjàgbara kúrò nínú ìgbèkùn sílệ nínú èyí tí wọn ó ti mú lyípadà dé bá asà wa. Culdre Àwọn ònkòwé tó ti kọ irú ìtàn yìí ni Olóyè I.O. Délànò tó kọ Lojo Qjoun àti Ayé Dayé Òyìnbó; Adébáyò Fálétí tó kọ Ọmọ Olókùn Esin àti Basòrun Gáà; Akínwùmí Isòlá sì ko Efúnsetán Aníwúrà. | |
| dc.description.sponsorship | Self | |
| dc.identifier.citation | Hamzat, S. A. O. (2000). Àyẹ̀wò ìbáyému nìnù o̩mo̩ olókùn ẹṣin àti ayé dayé òyìnbó YORÙBÁ GBÒDE: Jọ́nà Ẹgbẹ Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá, Nàìjíríà. 2 (3), 151-158, Published by the Association of the Teachers of Yorùbá Language, Department of African Languages and Literatures, Lagos State University, Ojo. ISSN; 1118-2482. | |
| dc.identifier.issn | 1118-2482 | |
| dc.identifier.uri | https://uilspace.unilorin.edu.ng/handle/123456789/16209 | |
| dc.language.iso | en | |
| dc.publisher | The Association of the Teachers of Yorùbá Language, Department of African Languages and Literatures, Lagos State University, Ojo | |
| dc.title | Àyẹ̀wò ìbáyému nìnù o̩mo̩ olókùn ẹṣin àti ayé dayé òyìnbó YORÙBÁ GBÒDE | |
| dc.type | Article |