Ifoju tiori Asa Ibile se Atupale Eto Igbeyawo ati Isomoloruko fun Alafin Oyo

dc.contributor.authorAdeyemi, RO
dc.date.accessioned2026-04-19T13:19:19Z
dc.date.available2026-04-19T13:19:19Z
dc.date.issued2025
dc.description.abstractO ̣̀kan lára ohun a wáyé wá ṣe ni ètò ìgbéyàwó àti ọmọ bíbí je ̣̀ níle ̣̀ Yorùbá. Ìdí sì nìyí tí wo ̣̀n fi máa ń sọ pé “Ẹní wáyé tí ò bímọ wáyé asán”. Iṣe ̣̀ yìí ṣe àtúpale ̣̀ àṣà ìgbéyàwó àti ìsọmọlórúko ̣̀ bí a t ií ṣe é láàfin O ̣̀yọ̀ láti ìgbà ìwáṣè títí di òní. Àwọn àṣà Yorùbá lo ̣̀kan-ò-jọ̀ kan ló ti ń dohun ìgbàgbé látàrí àìní àǹfààní láti gán-án-ni bí a ṣe n. ṣe wo ̣̀n láto ̣̀do ̣̀ àwọn àgbà. Èròńgbà iṣẹ̀ yìí ni láti wá ojútùú sí ìṣoro yìí níwọ̀ nba ìgbà tó je ̣̀ pé ó ṣòro fún ake ̣̀ko ̣̀o ̣̀ láti kù gììri wọ inú ààfin O ̣̀yọ̀ fún iṣe ̣̀ ìwádìí. Ìdi gan-an sì rèé tí a fi lo ọgbọ̀ ìso ̣̀tàn ‘ó-s.ojú-ù-mi-kòró láti le lo ìrírí òǹko ̣̀wé yìí ge/̣̀ge ̣̀ bí Ayaba. Tío ̣̀rì sosio ̣̀lo ̣̀jí lítíréṣo ̣̀ ni yóò ràn wá lo ̣̀wo ̣̀ dáadáa láti le ṣe àtúpale ̣̀ ọ̀ hún dójú àmì. Àbọ̀ ìwádìí je ̣̀ ká rí ètò ìgbéyàwó àti ìsọmọlórúkọ láàfin O ̣̀yọ̀ lo ̣̀nà tí ó yàto ̣̀ sí ti gbogbogbòò níle ̣̀ Yorùbá. Ise ̣̀ yìí dá a lábàá kí á túnbo ̣̀ ṣe àwárí àwón àṣà àti ìṣe Yorùbá pàápàá nínú ààfin àwọn ọba kí á sì ṣe àfíwéra re ̣̀ pẹ̀ lúu tòde òní nírètí àti to ̣̀jú àwòn ohun wo ̣̀n-ọn-nì kí ó má baà di ohun ìgbàgbé torí tí ọmọdé ò bá bá ìtàn, o dáa kí ó bá àro ̣̀bá tíi ṣe baba ìtàn.
dc.identifier.urihttps://uilspace.unilorin.edu.ng/handle/123456789/17393
dc.language.isoen
dc.publisherDepartment of Linguistics and Languages, Adekunle Ajasin University
dc.relation.ispartofseries16
dc.subjectÀàfin
dc.subjectìgbéyàwó
dc.subjectìsọmọlórúkọ
dc.subjectàsà
dc.subjectsosio ̣́lo ̣́jì
dc.titleIfoju tiori Asa Ibile se Atupale Eto Igbeyawo ati Isomoloruko fun Alafin Oyo
dc.typeArticle

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
B-UPDATE-2025-B-ÌFOJÚ TÍỌ́RI ÀṢÀ ÌBÍLẸ̀ ṢE ÀTÚPALẸ̀.pdf
Size:
1.02 MB
Format:
Adobe Portable Document Format
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description:

Collections