Adeosun, Hezekiah Olufemi2019-04-152019-04-152008N/Ahttp://hdl.handle.net/123456789/1750N/AKì í se ohun tuntun tàbí ohun èèwò ni kí àwùjo kan mú lára àbùdá àsà àwùjo mìíràn. Nípasè èyí, ìdàgbàsókè àti ìtèsíwájú nípa ètò oró-ajé, ìsèlú, ìmò èro àti ìmò sáyénsí yóò máa bá irú àwùjo béè. Sùgbón ohun tó burú jáì ni kí àsà tí a mú láti ara àbùdá rè kúkú wá gba orí lówó àsà tí a yá a wò. Pàtàkì ohun tí a gbé yèwò nínú isé yìí ni àkóbá tí ètò ìsekáríayé (tàbí ohun tí Adéyemí (2006) pè ní ìso-ayé-dòkan) se fún àsà Yorùbá, pàápàá àsà ìgbéyàwó. A fí ewì àpilèko Ayé n yípo tí Àyángbilé àti Òpádòtun ko se àtègùn. A wo ire àti ibi tó wà nínú ìsekáríayé, gégé bí ó se hàn nínú ewì àpìlèko yìí, pèlú ìmòràn ònà àbáyo nípa pípadà sí àsà ìbílè Yorùbá.otherisekariayeasa igbeyawo YorubaIsekariaye ati asa Yoruba: Agbeyewo ewi apileko Aye n yipoNILArticle