Okewande, O. T.Adebayọ K. A.2026-04-152026-04-152021máàsì,ewì, ìṣèlú, ìjọba olóṣèlú, ìjọba ológunhttps://uilspace.unilorin.edu.ng/handle/123456789/17222Ní lẹ̀ tó mọ́ ló nì í ní lẹ̀ Adú lá wọ̀ à ti ní pà tà kì , ló rí lẹ̀-è dè Nà ì jí rí à , ì pè ní jà ń lá -ǹ là ni lá ti mú kí ì ṣè jọba tiwa-n-tiwa oló ṣè lú , digi à lọ́yè . Ní torí ná à , è rò ǹ gbà iṣẹ́ ì wá dì í yì í ni lá ti ṣà mú lò ewì Adé bá yọ̀ Fá lé tí - Bí rí layé ń yí , tí Ọlá tú njí ṣiṣẹ́ ló rí rẹ̀ ní 1982 fú n ì mú dú ró ore, ì rẹ́sẹ̀walẹ̀ à ti ì dà gbà só kè ì jọba oló ṣè lú ní orí lẹ̀-è dè Nà ì jí rí à . Yí yan ewì yì í jẹ́ è yí tó ní ì ṣewẹ́kú pẹ̀lú ì ṣẹ̀lẹ̀ ò ṣè lú à wù jọ ì lẹ̀ Nà ì jí rí à . Tí ọ́rì sosiọ́lọ́jì lí tí ré sọ̀ tí ó tẹ̀lé è rò Karl Marx ni a ṣà mú lò fú n ì tú palẹ̀ iṣẹ́ yì í . Abala ì là nà tí a má a lò ni è yí tí Eagleton (1976) ṣe agbá tẹrù rẹ̀: è yí tó gbà pé , ì bá ṣepọ̀ tó gbó pọn wà lá à rin lí tí ré ṣọ̀ à ti ì ṣè lú . Ì là nà yì í tú n ṣà Ʀƪhà n pé , lí tí ré ṣọ̀ kò le také té sí ọ̀rọ̀ ì ṣè lú , à tú palẹ̀ è tò bá yé ṣerí à wù jọ a sì má a Ʀƪ nǹ kan ì jì nlẹ̀ hà n ní pa ì ṣè lú à wù jọ yá là , lórí ìṣèlú àtijọ́tàbí èyí tó wà lóde. Ìlànà yìí kò sé lórí ìfúnkamọ́lórí ètò ìṣèlú àwùjọ, èyí tó jẹ́ kó kó , bí ọwọ̀n ì ṣẹ̀lẹ̀ tó lè mú à wù jọ tẹ̀sí wá jú tà bí fa à wù jo sẹ́yì n. È yí kò sì yọ ewì Yorùbá sílẹ̀. Ìlànà yìí lòdì sí ìjẹgàba-lé-ni-lórí, ìmúnisìn àti ìrẹ́nijẹlátọ̀dọ̀àwọn olórí àti aṣáájú tó wà nípò pàtàkì láwùjọ (àwọn alágbára) lórí àwọn mẹ̀kúnnù (aláìlágbára). Látàrí èyí, ì jà gbù dù à ti ì là kà kà lá ti jà jà bọ́ kú rò ní nú ì jẹgà ba-lé -ni-ló rí , kí à yí padà lè wà ni ohun tí ì là nà yì í ń rá n lẹ́nu bí Ifá . À bá já de iṣẹ́ ì wá dì í yì í Ʀƪhà n pé , ipa kè ré mí kọ́ ni ewì lè kó , fú n àmúṣẹ àwọn ètò ìṣèlú ìjọba olóṣèlú nílẹ̀Nàìjíríà. Kókó-ọ̀rọ̀: máàsì,ewì, ìṣèlú, ìjọba olóṣèlú, ìjọba ológunÀmúlò Ewì Yorùbá fún Ìdàgbàsókè Ìjọba Tiwa-n-tiwa Lórílẹ́-èdè Nàìjíríà.Àgbéyẹ̀wò Ewì Bírí Layé Ńyí Adébáyọ̀ Fálétí tí Ọlátúnjí kọ: Ọ̀PÁǸBÀTÀ: Jọ́nà Ìmọ̀ ÁfíríkàArticle